Chorus:
Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh.. /2x
Call: ki ma ma ise tori mo dara, tabi tori mo mo aduraa gba
Response: Anu..Anu..Anu Ni mori gba eh
Call: ki ma ma ise ile ti mo wa, tabi tori gbogbo iwe ti mo ka
Call: Ki ma ma ise tori moni baba Isale, lo mu kokan mi fi bale.
Call: Bi mo ba se njade nile
Aanu!
Call: Bi mo se nkore woke
Aanu!
Call: Mo nsori ire sere
Aanu…ko ma tele mi o
HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?
0