Anu Ni Mo Fe

Akintunde Oladipupo

Added on : Sep 8, 2020

Anu Ni Mo Fe – Akintunde Oladipupo
Sep 8, 2020 Abimbola Tolulope
In Lyrics

Ifaara(Prelude):
Olodu omo are.
Ipa mi pin Jesu fanu gbami ooo(x2)
Larin opo ijo eniyan fanu gbami ooo.

Alanu alai lenikan (jesu)×2
Eni nla Isreali,
Oke rabata to kan satani satani laya,
Oso gboruko Jesu jinijini bo ooo,
Aje gboruko Jesu owa riri ooo,
Olorun awon eni mimo to moye irawo,
Oloju ariran,
Wolewole to nwonu opolo,
Oba ni rinrin ajo mafilesile,
Oba ni lalejo wan tonile maje,
Oba ni rinrin ajo mafile lowo,
Oni gangan itura, mimo(x7),
Owo kenbe rebi ja bi eni lo sere.

Lead: Ipa mi pin Jesu fanu gbami ooo(x2)
Response: Larin opo ijo eniyan fanu gbami ooo.

Lead & Response:
Anu mo nfe, anu lolese (x2).
Ile pepe yi ti su mi oo,
Ile pepe yi ti su mi oo,
Oluwa, fanu gbami,baba alanu.

Vocal 1:
Anu re O’luwa lawa ntoro,
Ro ojo re lewa,
Eye tinfo atera to nrin le,
Nri won lopolopo.

Response:
Anu (×2)
Anu re baba wa orun la wa ntoro,
Eye tin fo atera to nrin le,
Nri won lopolopo.

Vocal 2:
Orun losan nipa asere ni,
Atosupa loru,
Igba ojo ati gba ikore,
Lowo re ni won wa.

Response:
Anu (×2)
Anu re baba wa orun la wa ntoro,
Nye tin fo atera to nrin le,
nri won lopolopo.

All:
Anu mo nfe, anu lolese (x2).
Ile pepe yi ti su mi oo,
Ile pepe yi ti su mi oo,
Oluwa, fanu gbami,baba alanu.

Lead: Fanu fami dide ooo, fanu fami dide baba.

Respons: Ko ma ma peju (x2) fanu fami dide o.

Lead: Fanu fami dide o, fanu fami dide baba.

Lead: Alanu sanu mi o, alanu saanu mi baba.

Lead: Jesu saanu mi o, alanu saanu mi replete.

Lead: Baba saanu mi o, Jesu saanu mi repete.

Lead: Ka’yemi tan mole o, ka’yemi tan mole re baba.

Lead: Ki’semi fo’go re han, Ki’semi fo’go re han baba.

Lead: Kin mase subu lona iye, Ka’ye mase si o mi baba.

Lead: Alanu saanu mi o, ka’ye ma se si o mi baba.

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend