Dide Oluwa (The Lord's Coming)

Princess Olubukola Adegbodu

Added on : Jun 4, 2019

Dide Oluwa (The Lord’s Coming) – Princess Olubukola Adegbodu
Jun 4, 2019 I-solo
In Lyrics

Chorus
Ha Araye,
igbeyin aye lawa yi o,
dide Oluwa ku si dede ayanfe e mura2x

Verse 1:
Bibo Olugbala sunmo etile ayanfe e mura
Idajo oga Ogo sunmo’le o elese yi pada
Ronu ko piwada loni Ola le pe ju fun e
Loni ni Jesu pe, ashako pada wale eeee

Chorus

Verse 2:
Ese ti gbaye kan o,
ko ma s’olododo mo o 2x
iwe momo ni gbogbo wa lasa ti se ta si ti kun a Ogo Olorun 2x
A ha le wa ninu Ese ee kani kore ofe maa po si2x
Isise kan lo wa laarin iku ati iye Ore gba Jesu ko ye eee

Bridge:
Anfani ki lo jeee…
Fun gbogbo eniyan 2x
To jere gbogbo aye o to padanu ijo a orun 2x
Jesu kami ye, kami ye fun ‘joba re..

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend