Chorus:
E’le Dami’duro , òta òlè dámidúró
Bàbá nikan ni mo bá dúró
Èyin nìkan ló le sé o
Verse 1:
I see no boundaries to what I can achieve
If God be for me who can be against me
Bàbá fó ojú òtá ni oritameta
O gbe mi leke
O Segun fun mi
O damilare
O funmilayo
Opemipo oOo, opemipo nitori pe
Chorus…2x
Verse 2;
Ìwo sáti gbàgbó nínú Oluwa
Nítorí enití o joko si ibi ìkòkò ògá ògo
Ohun ni yio ma gbé ni abé òjìjì elédùmarè
Òun sá, ni o gbe mi leke
O Segun fun mi
O damilare
O funmilayo
Opemipo oOo, opemipo nitori pe
Back to Chorus…2x
Bridge
Ko ma si òun tí oò lèse
Tí ó bá ti ni ìgbagbó
Dúró tí oluwa
dìde ki o sé éééee
HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?
0