Gbo Ohun

Oluwaseyi Kuti

Added on : May 16, 2017

Gbo Ohun – Oluwaseyi Kuti
May 16, 2017 Oluwarufus
In Lyrics

Ewi:
Agbagba merinlelogun eku ise o eku ijuba baba mi
Eyin le nfiyin, fogo fun baba mi lala i dawo duro
Towuro, tosan, tasale le nkorin iyin yin baba lala i simi enu
Are kini se mi? Kini n baka, etiri ti n onile dupe baba dakun mase fokuta ropo mi
Ara ile, eni gbogbo ti nbe nihahin dara po momi ka jo gbogo baba mi ga a
Ebe ni mobe lojo tipe yio ba dun eje nle pelawon torun
To nkorin
Mimo mimo mimo o o
Soba mi

Chorus
Gbo ohun angeli ti nkorin
Won korin titun si eledumare
Won korin titun si olorun to gaa ninu orun
Won fohun orin didun won korin hosanna
Won yi ite re ka, won korin halleluyah
Gbo ohun angeli ti nkorin 2x

Call: awon angeli korin mimo
Resp: won korin
Call: mimo mimo seni mimo
Resp: won korin
Call: hosanna metalokan
Resp: won korin
Call: agbanilagbatan
Resp: won korin
Call: moni won nwole
Resp: won nwole
Call: seni mimo
Resp: won nwole
Call: mimo mimo ninu awon orun
Resp: won nwole
Call: won njuba alade wura
Resp: won nwole
Call: won npa ruburubu niwaju ite idajo
Resp: gbo ohun angeli ti nkorin

Ewi 2:
Too, ibi awi lade wayi, gbogbo eyan ti nba be laye, be laaye ko kalo kajijo yin baba
Orin iyin, orin emi lode latori ite mimo mimo wa ara e mo bami gboyin baba mi
Nje o gbo bi kerubu, serafu se n ke mimo mimo bi?
Iwo arawon angeli npa ruburubu, amu mi ri ijo awon angeli nyo sesese
Afe ni aba la loju loleri, eni aba si leti nlo le gbo orin mimo mimo o tawon torun nko o
Ariwo iyin nla so lagbala oba mimo, kikan kikan losanna nkegbe iro halleluyah won
Mimo mimo ni o o mesaya baba mi
Ala funfun gboooo

Repeat chorus

Call: arugbo ojo igbani
Resp: won korin
Call: yagbo yaaju okunrin ogun
Resp: won korin
Call: obirikiti ajipojo ikuda
Resp: won korin
Call: gbongbo idile jesse okunrin ogun
Resp: won korin
Call: alade lorun ohun aye
Resp: won ko-o-orin
Call: kabiesi re oo oba mimo
Resp: won ko-o-orin
call: aseyi owu oba aye
resp: won ko-o-orin
call: ko seunti, ko paniti
resp: won ko-o-orin
call: ko paniti, ko jiniti
resp: Gbo ohun angeli ti nkorin

Won korin
Call: Mimo mimo
Resp: won korin
Call: seni mimo ninu orun
Resp: won korin
Call: obirikiti
Resp: won korin
Call: gbogbo idile jesse
Resp: won ko-o-orin
Call: alade lorun ohun aye
Resp: wom ko-o-orin
Call: adagba ma tepa
Resp: won ko-o-orin
Call: olowo nla
Resp: won ko-o-orin
Call: aseda, ameda, olorun ti nje emi ni
Resp: gbo ohun angeli ti nkorin

Download song here

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend