[songtitle]

[Artiste]

SHARE
TWEET
EMAIL
SHARE
PRINT

Jesu olufe okan mi
Jesu olugbala okan mi
O ta eje re sile
tori irapada mi

Ibukun atope ni foruko re titilai
iyin atogo ni forukore titilai

Jesu mi olugbeja mi
Jesu loluso aguntan mi
O wa pelu mi nigba gbogbo
O rin pelu mi emi ki yo beru

Ibukun atope ni foruko re titilai
iyin atogo ni forukore titilai

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

SHARE
TWEET
EMAIL
SHARE
PRINT