Jesu Tete De

Michael Akingbala

Added on : Jul 9, 2017

Jesu Tete De – Michael Akingbala
Jul 9, 2017 Oluwarufus
In Lyrics

Chorus:
Call: Jesu Jesu Jesu, te te de
Resp: Jesu Jesu Jesu, te te de

Call: Jesu Jesu Jesu, omi je jabo
Resp: Jesu Jesu Jesu, omi je jabo

Verse 1:
Iwo lo to, iwo looto
Iwo loonto, iwo gangan lotito
Yagboyaju okunri ogun
Adagba ma paro ooye
Oba to tele bi enu teni
Ota sonmo beeni taaso
Ogbigba ti gba alailara
Baba mi aja ma jebi
Aja ma fi ti bon se
Owo sokoto kembe re bi ija
To ba ti e wo nko ooo?
Kini grandfather enikankan yi o se x2
Aleni ba lo na, lai puro loju kan
Oro ti gbenu omo eniyan to n fohun
Oba ti kin ku, oba tiki n sha
Oba ti ki ti, ti kin di baje

Chorus:
Call: Jesu Jesu Jesu, te te de
Resp: Jesu Jesu Jesu, te te de

Call: Jesu Jesu Jesu, omi je jabo
Resp: Jesu Jesu Jesu, omi je jabo

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend