Se rere (Good Things)

Olabisi

Added on : Jul 1, 2018

Se rere (Good Things) – Olabisi
Jul 1, 2018 I-solo
In Lyrics

Vocal 1:
Bi Asian n se iwofa , won a ni alakori gbe’se re dee ,
bi o ba s’omo olowo, won a ni ko roju ko f’ata senu (2x)
Ibi ko ju ibi
Bi a ti b’eru sa LA bi omo
Eni a f’ise WO nii dagba
Eni a foju ojo bi ko to ge-ge

Response :
Bi aisan n se iwofa , won a ni alakori gbe’se re dee ,
bi o ba s’omo olowo, won a ni ko roju ko f’ata s’enu

Vocal 2:
Eni ba se ibi ooo , a ri ibi
Eniyan to ba se rere oooo , a ri’re muuu
A ko le gbin alubosa , ki a fi ka ila … O s’eewo o
Eniyan see rere oo … Eniyan see rere
Oooo ba see rere ooo ko le GBA rereee

Response:
Eniyan se rere oooo , eniyan se rere
O ba se rere oooo
Ko le GBA rere

(Bridge)

Vocal 3:
Ma pa, Ma mu , Ma jin in l’ese , Ma fun l’ese l’enu
Maa daaa duro, ko ni le goke
Maa b’ogo aye re jeeeeeee

To ba de wa seee tan oooo
Ki lo fe GBA nibe gan
Okan re ko ni bale , aye ti e gan ko ni tee siwaju
Inu re ko ni Lee dun , a fi to ba se rere

Response:
Eniyan se rere ooo
Eniyan se rere , o ba se rere ooo , ko le GBA rere
(Repeat twice)

Vocal 4:
Atubotan ika o da
Igbeyin olubi ko sunwon rara

Response :
Atubotan ika o da igbeyin olubi ko sunwon rara

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend