Mo wo yika aye
Oke oun petele
Alagbara ni o
Oba toti wa tele
Unshakeable
Unmovable
Unstoppable God
Talabafi O we o
Oba ti nki gba’betele
Ana, oni, ola o
Oba to ti wa tele
Reliable, Dependable, Unsearchable God
Mo wo le
Mo juba Re
Talabafi O we
Kosi ooo
Talabafi O we eh eh eh
Talabafi O we eh
Talabafi O we
Kosi oo
Talabafi O we eh o
All:
Talabafi O we
Kosi oo
Talabafi O we
(Seb’eyin loba to gbon) Eyin l’Oba to gbon
(Ti ogbon kori mu) Ti ogbon kori mu
(Seb’Eyin loba to mo) Eyin l’Oba to mo
(Ti imo ‘ole pa) Ti imo ‘ole pa
Arugbo Ojo
Aseda orun
Eyin l’atobiju
Lead: Eyin l’atobiju
(Seb’eyin) Oba to ta sanmo
bi eni te’ni
(O fi gbogbo aye) O fi aye o, sapoti itise re
Aribiti, Arabata
Eyin l’atobiju
Lead: Talabafi O we
Oluwa a, Oluwa, Oluwa, Oluwa wa
Oruko Re ti niyin to ni gbogbo aye
Iwo ti O gbe Ogo Re ka ori awon orun
Lati enu awon omo owo, titi de enu omo irinse, ni wonti’un se ilana agbara
Kabieyin o si, Kabio o si, Kabieyin o si, Kabiyesi iyin Re,
Onile kangunkangun ode orun
Oro to ju oro tole jade lenu ologbon to ga ju laye
Oba ti o ti wa tele, kosi ni gba abetele lailai o
Emi a’ma pe e l’olorioko gafata, Olori ogun orun
Ijaya f’araye, Iberu fun gbogbo awon omo adari hu’run
Iwo ni, Iwo ni
Oba nla, Oba nla, Ti’un se’un nla, too lagbara nla, Oba mi Alagbara orun
toolagbara lati gba agbara lowo alagbara aye
Ogo fun O o, Kabiyesi o, Oba awon oba, Iba o o, Iba a…
No god like You
No king like You
And no man like You, Lord
Talabafi O we, Talabafi O we
All:
No man like You
No king like You
No god like You
Talabafi O we, Talabafi O we