Aanu ni mo bere

FAlola Samson Dat

Added on : Aug 23, 2018

Aanu ni mo bere – Falola Samson Dat
Aug 23, 2018 I-solo
In Lyrics

Aanu ni mo bere,mo bere,mo bere
Aanu ni mo bere
Wa s’aanu fun mi (2x)

Sebi wo lo saanu,f’hannah ni Shiloh
Aanu ni o bere
Oso Hannah d’olomo
Sebi so lo saanu,fun Jabezi
Otosi aye

Aanu ni o bere, owa s’owon re di pupo.
Aanu ni mo bere, mo bere, mo bere
Aanu ni mo bere, wa s’aanu Funmi

Saanu aye Mi
Saanu aye Mi o
Saanu aye Mi
Wa se’yanu laye Mi

(CHANT)

Aanu ni mo bere, mo bere, mo bere,
Aanu ni mo bere, wa s’ aanu funmi.

Awa n’bere fun aanu
Aanu to lo bi epe eti okun o
Aanu to te re re bi omi oju okun o
S’aanu fun wa,
Jesu s’ aanu fun wa o
Oluwa s’ agan d’olomo
Ori buruku o,so won d’olori ire
Ki gbogbo ikolo wa,ko pada wale.
Lori ile ede wa o
Jesu s’ aanu fun wa o.

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend