Adara

Oluwabunmi Element

Added on : Oct 21, 2019

Adara – Oluwabunmi Element
Oct 21, 2019 I-solo
In Lyrics

Intro (Interlude)

Chorus:
Botiwukole ore Mi Adara
Botiwu koburuto Ore Mi Adara
Bekunpe dale kan Ayo nbo loluwa with
Botiwukole Ore Mi Adara
Adara(2ce)
Botiwukole Ore Mi Adara

Interlude

Verse
Iya to jomo fogun Odun tikopomo kole pomo
Osi tojomo fogbon Odun tikopomo kole pomo
Adun loun gbehin ewuro, ore Mi gbo lomu suuru
Ikoko toma jata, shebi idi re akoko gbona
Bope boya ore Adara, Iwo sati gbokan le oluwa olorun re
Eni ma joyin inu apata,shebi wonni koni wenu Aake.
Lojo ririje lojo Airije ore gbekeloluwa
Lojo riri mu, lojo Airimu ore Mi gbekeloluwa.
Botiwukole otibawa damajemuwipe
Ileri Ayo ase laye wa kasati nigbagbo padara.
Call: oya mofe komo dajupe
ll: Adara ore Mi Adara

Back to chorus

The end

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend