Aju Asegun Lo

Raphael A. Macaulay

Added on : Jan 17, 2018

Aju Asegun Lo – Raphael A. Macaulay
Jan 17, 2018 I-solo
In Lyrics

Verse
Awa ju asegun lo
Nipa ife Oluwa wa
Ati bori ese at’iku
Nipa eje Jesu Kristi Oba

Bridge
Awa njoba pelu Jesu
Ninu ogo titi lai

Chorus
Awa ju asegun lo
Awa ti bor’ohun gbogbo
Hallelujah! Hallelujah…ah…ah
Hallelujah!

Hallelujah…

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend