Àlùjanjankíjan

Sola Allyson

Added on : Aug 7, 2017

Àlùjanjankíjan – Sola Allyson ft. Adekunle Gold
Aug 7, 2017 Oluwarufus
In Lyrics

Iya iya ta’kun wa’le, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wa’le, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko wo’mo, Alujanjankijan

[Sola Allyson]
Bami nan momi ye ko de’nu olomo
Oju merin lon bimo sugbon igba oju lon w’omo
Omo tao ko, a gbe ile ta ko ta
Omo tao ko, a ko eso tani ta
Omo nigbeyin, Omo lola, Omo lola
Omo niyi, Omo lade, Omo lewa, Omo leso oo
Oda bioda, o le da
O san bio san, a de san
Igboya ati adura ni yio gba
Yio da

Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo loye ko wo’mo (e tomo), Alujanjankijan

[Adekunle Gold]
Ori funmi l’omo rere bi ti Samuel o
Won kosa fun o gbe eko o
If you spare the rod you go spoil the child I hope you know ooo
Train them with the love of God I beg oooo
Tori alaigboran omo, asa ni
Agba o jo won loju, asa ni
Agbaya ni o da, asa ni
Alaigboran omo o, omo ni
Won le d’eyan lola, omo ni
Ta ba ko won dada, omo ni
Won le d’eyan lola, omo ni

Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko w’omo, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan

Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya iya ta’kun wale, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Eni to bimo lo ye ko w’omo, Alujanjankijan
E ma f’omo sile fun iya je, Alujanjankijan
Iya baba ta’kun wale, Alujanjankijan

Kekere lati npa eka iroko
To ba dagba tan ebo ni yio ma gba
Ohun ta bi fi sile l’ewure ngbe
K’ewure aye ma ma gbe wa l’omo lo
Omo ta o ro ekun aye a gbe lo
K’ekun aye ma ma gbe wa l’omo lo
Iya Iya ta’kun wale, Alujanjankijan
Iya Iya ta’kun wale, Alujanjankijan

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend