Iro Ayo

Mike Abdul, Omotola Jaiyeola

Added on : May 21, 2022

Iro Ayo – MIke Abdul Ft. Omotola Jaiyeola
May 21, 2022 I-solo
In Lyrics

Verse 1
Iro Ayo La o ma gbo nile wa
Sekere ilole ekun
Igbagbo lo so’wa da’segun
Let them know pa’loluwa

Awa oni loju ekun La’ye
Awa oni lereke ose
Ore ofe Oluwa towa
Let them know pa’loluwa

Enu ope wa o’gbolude
Orun si ayo de s’aye
Ayo Olorun s’a lagbara wa
Won ti mo pa’loluwa

Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh

Verse 2
Once has He spoken
Twice have i heard
All power belong to GOD
Sing His praise with a shout of joy

Mimo Loluwa Mimo
Gbogbo aye kun fun ogo re Mimo
Awon Orun won wa riri Mimo
Almighty lo’lorunwa

Ayobami Ayomide
Ayomipo Ayomikun
Gbogbo Ayo ni mo kojo sir
Igbala Ayo ti wole de

Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh

Vamp
Ayo Ayo Ayo
Ayo Ayo nise

Ayo
Ayo ni mo gbede
Eni ba rimi e gb’ayo
Eni ba gbo mi e gb’ayo
Oun mbase ayo
Ayo ni mo gbede
Gbogbo oun mo dawomile
Lo yori si’re
kiise mimose
Ore Ofe s’a
Ore Ofe s’a o
Eh eh eh eh
Ayo Ayo ni’se

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend