Ojo Ibi (Birthday)

Odun Ajayi

Added on : Jun 22, 2018

Ojo Ibi (Birthday) – Odun Ajayi
Jun 22, 2018 I-solo
In Lyrics

Mo dupe ore
Mo dupe ibi o

VERSE
L’ojo ‘abini pataki ni ninu ojo
Orisirisi lo sele lojo yen
L’agbegbe omo
Igbe meji lo waiye
Igbe ekun ati igbe ayo
Eku ewu omo lo gbeyin
Igbe t’omo ke waiye
Iya la layo ju, l’ojo t’abi ni
Baba l’o lope to tobi ju
P’o r’aiye omo
If you live to see your days
To celebrate
Boju re w’eyin ko wo ‘ru re
Ni ‘boji oku

CHORUS (2×)
Ojo ibi ‘ole jo ojo iku
To r’ojo ayo ni o
T’aba fun o lati k’ojo ibi
Ko f’ogo f’Olu..

VERSE
L’ojo ‘abi mi pataki ni
Ninu ojo mi
Orisirisi lo sele lojo yen
L’ojo mo waiye
Igbe meji to waiye
Ni’gbe ekun mi ati
Igbe ayo awon eniyan
Eku ewu omo lo gbeyin
Igbe ti mo ke waiye
Iya mi la layo ju,
l’ojo t’abi mi saiye
Baba mi l’o lope to tobi ju
P’o r’aiye omo
If you live to see your days
You will celebrate
Boju re w’eyin ko wo ‘ru re
Ni isa oku (Boya waa dupe).

CHORUS (2x)
Ojo ibi ‘ole jo ojo iku
To r’ojo ayo ni o
T’aba fun o lati k’ojo ibi
Ko f’ogo f’Olu..

VERSE
The little baby ojosi
O ti d’okunrin o
I never knew I can see today
Lati f’ogo f’Olu…
Oluwa mo dupe ore
P’oo da mi si
Ogbon ori ‘ole s’akawe
Ore re e mo dupe
(Mo gbe’gba ope mi wa)

CHORUS (2x)
Ojo ibi ‘ole jo ojo iku
To r’ojo ayo ni o
T’aba fun o lati k’ojo ibi
Ko f’ogo f’Olu..

BRIDGE
Blow your candle
Make your wishes
Comes true
God’s mercies
And grace I enjoyed
(Repeat)

CHORUS (4×)
Ojo ibi ‘ole jo ojo iku
To r’ojo ayo ni o
T’aba fun o lati k’ojo ibi
Ko f’ogo f’Olu..

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend