Afe Aye

Psalmos

Added on : Mar 13, 2017

Afe Aye – Psalmos
Mar 13, 2017 Oluwasetemi
In Lyrics
Chorus
Ninu afe aye
Baba j’nle tele o
Ninu afe ile aye
Je nle tele o
Verse 1
What shall it profit a man to gain the world and lose his soul.
Ile aye yii dun ladunju
Sugbon igbeyin re koro bi iwo
Ile aye baje o balumo
O olu orun dakun maje sise
Maje fi adun ileaye o baba mi
Ki n fi ba ti orunje
Ko si bi aye tile dun to
Orun a dun ju ile aye lo
Repeat Chorus
Verse 2
The heart is deceitful above all things and desperately wicked who I mean who can know it
Orun o gbe e
Iro laye mo n
Afojo bori
Elesan wo o lorun
Idajo o le ro Iku l’ere ese
Eda adariwurun
Eeje a sora siwa wu
Ka mo ba oja je
Ka tun ba ale je
E ni awo e gbodo woran
chorus

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend