Alagbada Ina

Adejumoke Dada

Added on : Sep 28, 2020

Alagbada Ina – Adejumoke Dada
Sep 28, 2020 Abimbola Tolulope
In Lyrics

Alagbada ina alawotele orun,
Oba nla alara gbayida o,
Eni kerin ninu ina ileru,
Ina nla ton joo igbe oo,
Ti igbe o si runn.

Otun ni o, olorun aji dara,
Otun Len deru aye eda gbogbo,
Lotun lotun Len shi ilekun ojo gbogbo,
Aji dara fi aye mi da ara ire.

Bawo wo lo sheje ti omi fi de inu agbon,?
Ona wo lo gbegba ti iji ole da omi inu agbon nu,
Iyan eti okun ta lo le ka won,
Gbogbo omi inu okun mo ni how many liters ni gan?
Be sini omi n be lorun,
O gbe gbogbo aye so ri ikun omi,
Oda ile osi
O tun da awon oke,
Aji dara iwo la lara gbayida oo.

Ina nla to pin okun niya,
Ina nla to wo odi jeriko,
Ina nla ti o te ogun ayemi riiii,
Ina nla ton joo igbe o,
Ti igbe osi runn.

Oba ha 4x
Oba ha 5x
Oba ha 4x
Oba haaa iyanu ni ooo..

HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?

Thank you for sharing. Show us some love by joining our community.

Send this to a friend