
Emi naa a se gudugudu meje fun Jesu
Emi naa a fiye fo (I too will mount up on wings)
Emi naa a figbagbo gbe (I too will live by faith)
Emi naa a se gudugudu meje fun Jesu (I too will do exploits for Jesus)
Emi naa a ba Jesu rin (I too will walk with Jesus)
Emi naa a rinrin ododo (I too will walk in righteousness)
Emi naa a se Gudugudu meje fun Jesu (I too will do exploits for Jesus)
Emi naa a se gudugudu meje fun Jesu o
HOW HAS THIS IMPACTED YOUR LIFE?
0